Nigeria Gospel Music Minister, Elizavocat is out with her new single titled ORUKO RE” The Name of the lord is a strong tower and there is no greater power in heaven and on earth”

Oruko Re is a song that affirms all things is possible when the Name of Jesus is in charge. With him we know nothing will be impossible even as we journey through the storms. His name is more than Jazz.

 

Click to Listen, Download, and Share

LYRICS: Oruko Re by  Elizavocat

 

Oh oh /2*
Oruko re
Your name is more than Jazz
Oruko re jogunlo /2*
Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo
Je koruko re lana ko Lana fun mi o
JESU, iwo logun mi o oo

Ogun ajisa
ogun ajipe
ogun ajiyin
ogun ajibo
mope o loni ki n rowo
kire wamiri
kaye fohungbogbo toje re wamiri
Ogun ti o l’overdose
ogun ti oni prescription
ogun ti ole baje lailai
ogun ti ole womi
ogun ti ole sunko

CHORUS:
Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo
Je koruko re lana kolana fun mi o
Seborukore sa nigbekele mi
JESU,

iwo logun tose gbarale,
ogun ti ole dissapoint
ogun to ngbe ogun mi
ogun to bori ogun
ogun to bori epe
ogun to n woni san lorukore
ogun to n tunisile
ogun to n yoni ninu ofin
ogun to n renilekun
ogun to n ti ni leyin ogun to n pani lerin
ogun to n yaye e ni pada si rere
ogun to n saye eni dotun
ogun to n yi itan aye eni pada
ogun to n sogun dogo
ogun to n sofo dogo

Call: OLUWA

Resp: Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo
Je koruko re lana kolana fun mi o

Your NAME,

Oruko re to san bi ara,
oruko re to jabi iji,
oruko re lo nu omije nu,
oruko re lo n taye eni se,

Oruko tokunrin npe, tobinrin npe

Tomode npe, Tagba npe, tagba npe to de n je lojojumo

Oruko to n dani nide,
oruko to n wonisan,
oruko to n lana fun ni, o
ruko to fun ni ni ireti,
oruko toje jewe ategbo lo.

CHORUS:
Je koruko re lana, ko lana fun mi ooo
Jekorukore lana kolana fun mi o
Ogun to nje /2*
Oruko Jesu ohun nikan logun to n je

Ogun ti ole expire lailai,
ogun to nje,
oruko Jesu nikan logun to nje

Ogun ti ole yeye eni,
ogun ti oni expire lailai,
oruko Jesu nikan logun to n je